Àkọlé àwòrán, Láìpẹ yii ni fidio jade to ṣe afihan akẹkọbinrin ileewe Federal Girls College Akure to n fọ awọn ẹrọ ibanisọrọ tí àwọn akẹkọ̀ọ́ ń lọ̀.